
اليوربا
Ki nii ohun ti o jẹ 'Mubin' Program?
- Ohun ni program electronic ti owa fun kiko ede Arabic fun awon ti won so edemiran yato si Arabic, leyi ti on ba inkan ti awon akẹkọ n fẹẹ mu.
AkokoOwo ikẹkọAfojusunAnfaaniBawo lati le Waye ni ibi ẹkọ yii
- Lati August 1, 2016 titi di Oṣù 31, 2016.
- USD80 fun akẹkọ kan.
- Sugbon ibamun fun ipile etoo yii, ofe ni owo ẹko ma jẹ fun awon ẹgbẹrun meji akẹkọ (2,000) ti o ba kọkọ forukọsilẹ.
Awọn afojusun fun eto eko yii ni wọnyi :
- Ki akẹkọ le kọ awon ijinle ede Arabic, le yii ti yoo ran lowọ lati pe ko le ma kọ ekọ fun ara re.
- Ki akekọ le kọọ awọn ijin le nipa ibaraẹnisọrọ, ko lee ba le ma sọrọ pelu awọn miran.
- Ki awọn akekọ le ma nipa awọn aye esin mimọn ninu islam.
- Ki akekọ le ma nipa igbesi aye Anabi wa Muhammad. (S.A.W).
- Akẹkọ ani an anfani lati bori isoro ekọ Arabic.
- Lilo awon ero ikekọ ti electronic yoo .
- pese ohun irọrun ọna lati ko ẹko nibikibi ati ni eyikeyi akoko.
- Awọn ohun ilo eko yẹn ma wa larowoto fun akẹkọ.
- Awọn Olukọ ni lekọ naa gbọ awọn ede miran naa ninun awọn ede ti an lo lagbaye.
- Ko awọn alaye ti abere ni ibi fọọmù ìforúkọsílẹ ti owa ni online.
- Ṣayẹwo e-mail lati ma orukọ olumulo (User name), ati ọrọigbaniwọle (password).
- Lọ si oju ọna iforuko sile (application Portal) lati ṣayẹwo fun awọn ìforúkọsílẹ.
- Gba iwe igbanii wole ti akọkọ (Admission letter) nipasẹ e-mail.
- Sise idanwo akọkọ ti igbeyewo, lati ma ni pa ipele (level) ti oti yẹ ki opinlẹ ẹkọ rẹ nipasẹ e-mail.
- Rii daju pe o gba lẹta agbani wọle ti oma se alayee nipa asiko ti o bẹrẹ ati awọn ọjọ ti ibẹrẹ.
- Wiwole latipase portal awọn akekọ lati bẹrẹ awọn kilasi Arabic.